Ojo Maduekwe
Chief Ojo Maduekwe /θj/ (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 6, 1945, tó sì ṣaláìsí ní ọjọ́ June 29, 2016) jẹ́ olóṣèlú orílè-èdè Nàìjíríà láti ẹ̀yà Igbo, ní Ohafia, Ipinle Abia. Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní University of Nigeria, Nsukka, ó sì gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ òfin ní ọdún 1972.[1] Iṣẹ́ òṣèlú tó yàn láàyòṢọ́n yàn án sípò Mínísítà tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ilẹ́ òkèèrè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríàní ọjọ July 26, 2007 láti ọwọ́ President Umaru Yar'Adua.[2] Ó kúrò lórí oyè ní oṣù March 2010 lásìkò tí Ààrẹ Goodluck Jonathan wó ẹgbẹ́ náà kalẹ̀.[3] Òun ni National Secretary ti ẹgbẹ́ olóṣèlú Peoples Democratic Party (PDP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i igbákejì olùdarí fún ìpolongo ìdìbò ti ọdún 2011 lábẹ́ Goodluck/Sambo. Wọ́n yàn án fún SGF, àmọ́ wọ́n padà mu sílẹ̀ nítorí ìkùnsínú àwọn ènìyàn láti apa Ìlà-oòrun ilẹ̀ Nàìjíríà. Tẹ̀lẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n yan Maduekwe gẹ́gẹ́ bí iMínísítà tó ń rí sí àṣà àti Tourism gba ọwọ́ ààrẹ Olusegun Obasanjo ní ọdún1999.[4] Ọ̀rọ̀
Àwọn ìtọ́kasí
|