Open Austrálíà
Open Australia je ikan ninu awon idije Grand Slam merin to uwaye ninu ere-idaraya alagbase Tenis. O unwaye lodoodun ni Australia labe ase Tennis Australia, teletele tounje Egbe Ajose Tenis Australia (Lawn Tennis Association of Australia, LTAA) beesini idije akoko re waye lori papa isere kriket ni Melbourne ni 1905. Loni won unpe ibe ni Albert Reserve Tennis Centre.[2] ItanOpen Australia koko bere bi Idije-eye Australasia (Australasian Championships) ko to wa di Idije-eye Australia (Australian Championships), ni 1927 to si di Open Australia (Australian Open) ni 1969.[3]. Open Australia di sisi sile, eyun open, fun awon osise agba tenis ni odun 1969, odun kan leyin ti awon idije Grand Slam meta yioku ti di open fun awon osise agba tenis.[4]
Itokasi
Information related to Open Austrálíà |