Idibo fun ipo Gomina ipinle Eko ni odun 2015Idibo fun ipo Gomina ipinle Eko waye ni ojo kokanla osu kerin odun 2015. Oludije ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) Akinwunmi Ambode, ti o jẹ oniṣiro agba fun ipinlẹ Eko tẹlẹ, bori oludije ẹgbẹ oṣelu People’s Democratic Party (PDP) Jimi Agbaje ati oludije Alliance for Democracy (AD) Bolaji Ogunseye. Gomina ati igbakeji gomina ni a yan lori tikẹti kanna. Idibo fun asoju egbe APCOludije egbe APC Akinwunmi Ambode bori awon oludije mejila miran lati gba tikeeti egbe naa. O bori pelu ibo 3,735 lati bori oludije to sunmo re, Obafemi Hamzat (ti o gba ibo 1,201), ati olori ile igbimo asofin ipinle Eko Adeyemi Ikuforiji, eni to wa ni ipo keta to jinde pelu ibo mejilelogosan. Awọn oludije
EsiOgbeni Akinwunmi Ambode ni o jawe olubori ti o de fi si ipo lati se asoju egbe APC ninu idibo gomina ipinle eko. Idibo fun asoju egbe PDPAwọn oludije
EsiOgbeni Jimi Agbaje ni o jawe olubori ti o de fi si ipo lati se asoju egbe PDP ninu idibo gomina ipinle eko. Gbogbo idiboEsiOgbeni Akinwunmi Ambode ni o jawe olubori ninu idibo gomina ipinle Eko ni odun 2015[1][2]
Wo eyi naa
Awọn itọkasiInformation related to Idibo fun ipo Gomina ipinle Eko ni odun 2015 |